Ọjọ́jùmó làkín kánjú fí ń làkàkà

(Everyday the hardworking fellow strives)
Ìrìn arìnká léṣe ọmọlúwàbí
(The gentleman roams about)
Bẹkùn pé dálè kán
(Though weeping may endure for a night)
Bẹkùn pé dálè kán
(Though weeping may endure for a night)
Ayọ̀ olùwà nì òkun mí
(The joy of the Lord is my strength)
Ayọ̀ olùwà nì òkun mí
(The joy of the Lord is my strength)

Pre-Chorus
Incase you never hear
E don remember me
My life don beta
Èdùmàrè tí ṣé òòò
(The Almighty has done it)

Chorus
Ẹwà báwà yọ
(Come rejoice with us)
Bàbá ti ṣe ó
(The Father has done it)
Òhun táyè rope kò ṣe ṣé
(What the world thought is impossible)
Ẹwà bá wà yọ
(Come rejoice with us)
Àgbè sì ayọ̀
(We hear good tidings)
Ìlérí olùwà tí di mú ṣẹ
(God’s promise has come to pass)