Kayode Obagbemi – Gba Gbogbo Ogo


“Gba Gbogbo Ogo” by Kayode Obagbemi is a song of worship to the Blessed Trinity.

Kayode Obagbemi – Gba Gbogbo Ogo Lyrics

Gba Gbogbo Ogo
Gba Gbogbo Ogo
Gba Gbogbo Ogo
Iwo L’ogo ye

Ogo ni Fun Baba
Ogo ni Fun Omo
Metalokan Ijinle Ife
Ogo ni Fun yin

Ogo ni Fun Baba
Ati Fun Omo
Ati Fun Emi mimo
Bi o ti wa l’atete ko se
O n be ni isi yii
Aye ainipekun, Amin

Ogo ni Fun Baba
Ogo ni Fun Omo
Metalokan Ijinle Ife
Ogo ni Fun yin


*COPYRIGHT DISCLAIMER*
--------------------------------------------
We do not own this song nor the images featured on this Blog. All rights belong to its original owner/owners. No copyright infringement intended. For promotional purposes only.
--------------------------------------------

Previous Post Next Post